Posts

A Song: I Give You My Praises

Image
A Song: I Give You My Praises Revelation 1:8 I am Alpha and Omega, the beginning and the ending, saith the Lord, which is, and which was, and which is to come, the Almighty. Praising the lord makes one happy, it gives one a sense of belonging. 1) Oh God the most high I give you my praises The beginning and the end I give you my princess oh Lord 2) Before you know my God Will I dance and rejoice The beginning and the end I give you my princess oh Lord 3) Without you oh my God There can never be me The beginning and the end I give you my princess oh Lord 4) You've carved me oh my god In your image oh Lord The beginning and the end I give you my princess oh Lord 5) All glory to you Oh my heavenly Lord The beginning and the end I give you my princess oh Lord 6) My father you deserve My praises now and ever The beginning and the end I give you my princess oh Lord (The End)

O Kan Ìwọ Náà (2)

Image
Ó KÀN ÌWỌ NÁÀ (2) Lati ọwọ ÒGÚNDÁRE OLÚSẸ́GUN OLÚFẸ́MI © ÒGÚNDÁRE OLÚSẸ́GUN OLÚFẸ́MI (2015) Email: segundare111@gmail.com Facebook: Olusegun Ogundare Twitter: Ogundare Olusegun Telegram: Olusegun O. Ogundare Vk.com: Olusegun Ogundare LinkedIn: Segun Ogundare Tumblr: olusegundare Veenner chat: Ogundare Olusegun O. WhatsApp: +2347037106880 Cellular: +2348026301717 ÒRÍ KẸRIN IDAJỌ ATI ÈRÈ AFURUNGBIN NÃ No ori yi ni a o ti wo idajọ ati ere afurungbin na. (1) Ìdájọ́ afurungbin na ko duro lori ìwà ati ise awọn olugbọ rẹ bikose wipe idajọ rẹ duro lori asẹ Ọlọrun to tẹle tabi asẹ Ọlọrun to pamọ. Eleyi ni wipe, nigbati a bá ran afurungbin na si ilu kan, tabi iletò kan tabi ijọ kan tabi orilẹ ede kan tabi boya eniyan kan, ohun to se pataki fun afurungbin na ni lati lọ jisẹ ti a ran si ilu tabi ijọ tabi orilẹ ede tabi ẹni na.... Boya awọn tabi ẹniti a ran-an si nã kò wa gbọ ọrọ Ọlọrun nã, tabi boya wọn ko gba ọrọ Ọlọrun na gbọ tabi gba ọrọ Olorun na wọle, ele...