Posts

Showing posts from October, 2020

Orin Kan: O Rọrun Fun Ibakasiẹ Lati Wọ Oju Abẹrẹ

Image
  ( “O rọrun fun ibakasiẹ lati wọ oju abẹrẹ ju fun ọlọrọ lati wọ ijọba Ọlọrun lọ” (Mar. 10:25))   Ọrọ Àsọsíwájú Lati Ọwọ Onkọrin yi: Ngo mọ àwọn àmìn orin ti inu iwe daradara, sugbọn pẹlu awọn orin ti a ma nkọ nigbati mo wa lakọrin ati ninu ijọ gan bayi, mo ko orin titun yi jade. Bi o ba ti mọ orin to mbẹ nisale yi, ajẹ wipe o ti dara niyẹn darapọ mọ mi ki a jijọ kọ orin yi si Oluwa.   Ohùn Orin Inú Ìwe to yẹ ki a mọ Niyi “ ’Wọ Jesu t’a ti nreti Lati gba wa lọw’ ẹsẹ ‘Gbawo ni ‘gbala yo de Ti ao da ide ẹsẹ ” Ẹniti o Kọrin Yi: Orin Titun na Nìyí 1. ‘Gba Jesu wa ni aiye P’ẹlawọn ‘mọ-ẹhin rẹ Ọmọkunrin kan tọ wa Lati ber’ ohunkan lọwọ rẹ   2. ‘Gba to de ọdọ Jesu O sọ p’ol’kọni rere Ohun rere ki lem’ o se Kinle niye ainipẹkun   3. Jesu si fun l’esi pe Ẹni rere kan ko si Bikos’ ẹnikan soso Ẹni na si l’ Ọlọrun   4. ‘Gbọn bi ‘wọ ba fẹ niye ‘Wọ nilati p’ofin mọ Base kọ sinu ‘we ofin Gẹgẹ bi ‘wọ tise ka   5. ‘Gbọn ‘dọkunrin nab ere

Orin Kan: Àgbà Obìnrin

Image
( “Bẹ gẹgẹni ki aw ọn àgbà obìnrin jẹ ẹni-ọwọ ni ìwà, ki nwọn ma jẹ asọrọ-ẹni-lẹhin, tabi ọmuti, bikose olukọni ni ohun rere ” (Titu 2:3)) Mrs. Adegunle   Ọrọ Àsọsíwájú Lati Ọwọ Onkọrin yi: Ngo mọ àwọn àmìn orin ti inu iwe daradara, sugbọn pẹlu awọn orin ti a ma nkọ nigbati mo wa lakọrin ati ninu ijọ gan bayi, mo ko orin titun yi jade. Bi o ba ti mọ orin to mbẹ nisale yi, ajẹ wipe o ti dara niyẹn darapọ mọ mi ki a jijọ kọ orin yi si Oluwa.   Ohùn Orin Inú Ìwe to yẹ ki a mọ Niyi “L’owur ọ ọjọ ajinde T’ara t’ọkan yo pade Ẹkun, ‘kanu on irora Yo dopin ” Ẹniti o Kọrin Yi: Orin Titun na Nìyí 1. O dara k’awọn agba obinrin Jẹ ẹn’-ọwọ ni iwa K’awọn ma jẹ ẹntio nsọrọ Ẹni lẹhin   2. O dara k’awọn agba obinrin K’ nwọn mase jẹ omuti B’kose k’ nwọn j’ olukọni L’ohun rere   3. O dara k’awọn agba obinrin Letọ awọn ọdọmọbinrin Lati le ma fẹran awọn Ọkọ ti nwọn   4. O dara k’awọn agba obinrin Le ma k’ awọn ọdọmọbinrin Lati le ma fẹran awọn ọm

Orin Kan: Ẹgbẹ Buburu Ba Iwa Rere Jẹ

Image
( “Ki a ma tan nyin jẹ: ẹgbẹ buburu ba iwa rere jẹ” (1 Kor. 15:33))   Ọrọ Àsọsíwájú Lati Ọwọ Onkọrin yi: Ngo mọ àwọn àmìn orin ti inu iwe daradara, sugbọn pẹlu awọn orin ti a ma nkọ nigbati mo wa lakọrin ati ninu ijọ gan bayi, mo ko orin titun yi jade. Bi o ba ti mọ orin to mbẹ nisale yi, ajẹ wipe o ti dara niyẹn darapọ mọ mi ki a jijọ kọ orin yi si Oluwa.   Ohùn Orin Inú Ìwe to yẹ ki a mọ Niyi “ Ọlọrun ọdun t’o kọja Iret’ eyiti mbọ Ib’ isadi wa ni iji A t’ ilẹ wa laelae ” Ẹniti o Kọrin Yi: Orin Titun na Nìyí 1. Ẹ ma jẹ k’ẹnikẹni ko Tan nyin jẹ ẹnyin ara Ẹ m’ọyi p’ẹgbẹ buburu Ma mba ‘wa rere jẹ   2. Amnon’ jẹ ọkan lara awọn Ọmọkunrin Dafid’ Oun l’aburo obinrin kan Ti o njẹ Tamari   3. Amnoni si nifẹkufẹ Si Tamar’ aburo rẹ Ifẹ gbigbona to ni si Mu ko bẹrẹ aisan   4. ‘Gbọn Amnoni ni ọrẹ kan Ti orukọ rẹ njẹ Jonadabu ọmọ Simea To j’ ẹgbọn fun Dafid’   5. Alarekereke enia Ma ni Jonadabu jẹ ‘Gba t’oun gbọ pe Amnon saisan O

Orin Kan: Ẹnyin Baba

Image
( “Ati ẹnyin baba, ẹ mase mu awọn ọmọ nyin binu: sugbọn ẹ mã tọ wọn ninu ẹkọ ati ikilọ Oluwa” (Efesu 6:4)) Elder Richard Ayodele   Ọrọ Àsọsíwájú Lati Ọwọ Onkọrin yi: Ngo mọ àwọn àmìn orin ti inu iwe daradara, sugbọn pẹlu awọn orin ti a ma nkọ nigbati mo wa lakọrin ati ninu ijọ gan bayi, mo ko orin titun yi jade. Bi o ba ti mọ orin to mbẹ nisale yi, ajẹ wipe o ti dara niyẹn darapọ mọ mi ki a jijọ kọ orin yi si Oluwa.   Ohùn Orin Inú Ìwe to yẹ ki a mọ Niyi “Jesu ọrọ Rẹ ye O si ntọ isisẹ wa Ẹnit’o ba gba gbọ Y’o layọ on ‘mọlẹ” Ẹniti o Kọrin Yi: Orin Titun na Nìyí 1. Ẹnyin baba ‘wọn ọmọ Ẹri p’ ẹnkọ ‘wọn ‘mọ yin Bi ati ngbadura Ati l’ọr’ Ọlọrun   2. Ẹnyin baba ‘wọn ọmọ Ẹ m’awọn ‘mọ yin dagba Ni inu igbagbọ To mbẹ ‘nu Jesu Kristi   3. Ẹnyin baba ‘wọn ọmọ Bẹ ti mb’ awọn ‘mọ yin lo Ẹ ma mu wọn binu K’ọkan wọn ma ba rẹwẹsi   4. Ẹnyin baba ‘wọn ọmọ Ẹ tẹra m’eyi n’sise Ẹ ma tọ ‘wọn ‘mọ yin L’ẹkọ ati ‘kilọ Oluwa   5. Ẹnyin baba ‘wọn

Orin Kan: Nigbagbogbo, Ẹ Ma Ranti Eleyi

Image
( “Bẹ pẹlu ẹnyin ipẹrẹ, ẹ tẹriba fun awọn agba. Ani, gbogbo nyin, ẹ ma tẹriba fun ara nyin, ki ẹ si fi irẹlẹ wọ ara nyin lo asọ: nitori Ọlọrun kọ oju ija si awọ agberaga, sugbọn o nfi ore-ọfẹ fun awọn onirẹlẹ”.” ( 1 Pe teru 5:5 )) Emmanuel Rotimi and His Parents   Ọrọ Àsọsíwájú Lati Ọwọ Onkọrin yi: Ngo mọ àwọn àmìn orin ti inu iwe daradara, sugbọn pẹlu awọn orin ti a ma nkọ nigbati mo wa lakọrin ati ninu ijọ gan bayi, mo ko orin titun yi jade. Bi o ba ti mọ orin to mbẹ nisale yi, ajẹ wipe o ti dara niyẹn darapọ mọ mi ki a jijọ kọ orin yi si Oluwa.   Ohùn Orin Inú Ìwe to yẹ ki a mọ Niyi “Bibeli mimọ t’ọrun Ọwọn isura temi ‘Wọ ti nwi bi mo ti ri ‘Wọ ti nsọ bi mo ti wa” Ẹniti o Kọrin Yi: Orin Titun na Nìyí 1. Bẹ gẹ ‘yin ‘pẹrẹ at’ ọmọde Ẹ ma tẹriba f’awọn Obi nyin at’ oluwa yin At’ awọn agba arin nyin   2. Bọwọ fun baba on ‘ya rẹ Eyi lofin akọkọ To ni ileri ninu ‘Torina b’ọwọ f’obi rẹ   3. Bo ba fẹ ko dara fun ọ To si nfẹ ẹmi gigun O ni la

Orin Kan: Ìgbesoke Mbẹ

Image
( “Nigbati ipa-ọna rẹ ba lọ sisalẹ, nigbana ni iwọ o wipe, igbesoke mbẹ! Ọlọrun yio si gba onirẹlẹ la.” (Job. 22:29))   Ọrọ Àsọsíwájú Lati Ọwọ Onkọrin yi: Ngo mọ àwọn àmìn orin ti inu iwe daradara, sugbọn pẹlu awọn orin ti a ma nkọ nigbati mo wa lakọrin ati ninu ijọ gan bayi, mo ko orin titun yi jade. Bi o ba ti mọ orin to mbẹ nisale yi, ajẹ wipe o ti dara niyẹn darapọ mọ mi ki a jijọ kọ orin yi si Oluwa.   Ohùn Orin Inú Ìwe to yẹ ki a mọ Niyi “Apata aiyeraiye Se ibi isadi mi Jẹ ki omi on ẹjẹ T’o san lati iha rẹ Se iwosan f’ẹsẹ mi Ko si sọ mi di mimọ” Ẹniti o Kọrin Yi: Orin Titun na Nìyí 1. ‘Gbati ọna rẹ ba lọ lẹ T’ireti si pin fun ọ ‘Gbana iwọ yo wipe Ireti si mbẹ fun mi Igbesoke mbẹ fun mi ‘Tor’ oun yo gbonirẹlẹ la   2. Awọn to nfi omije Fun irugbin wọn lọwọ Pẹlu ‘gbagbọ wọn wipe Ireti si mbẹ fun mi Igbesoke mbẹ fun mi ‘Tor’ oun yo gbonirẹlẹ la   3. Awọn to nfẹkun rin lọ Pẹlu ‘rugbin wọn lọwọ Pẹl’ ayọ ‘wọn na wipe Ireti s

Orin Kan: Ìdè Ìfẹ́

Image
( “Mo fi okùn ènìyàn fà wọ́n àti ìdè ìfẹ́. Mo mú àjàgà kúrò ni ọrùn wọn Mo sì fi ara balẹ̀ fún wọn ni oúnjẹ.” (Hos. 11:4))   Ọrọ Àsọsíwájú Lati Ọwọ Onkọrin yi: Ngo mọ àwọn àmìn orin ti inu iwe daradara, sugbọn pẹlu awọn orin ti a ma nkọ nigbati mo wa lakọrin ati ninu ijọ gan bayi, mo ko orin titun yi jade. Bi o ba ti mọ orin to mbẹ nisale yi, ajẹ wipe o ti dara niyẹn darapọ mọ mi ki a jijọ kọ orin yi si Oluwa.   Ohùn Orin Inú Ìwe to yẹ ki a mọ Niyi “Ìtànna t’o bo ‘gbẹ l’asọ T’o tutu yọyọ bẹ Gba doje ba kan, a si ku, A subu a si rọ” Ẹniti o Kọrin Yi: Orin Titun na Nìyí 1. ‘Tori Ọlọrun f’araiye To f’ọmọ Rẹ fun wa Oun f’ide ifẹ rẹ fa wa O si gbọkan wa la   2. Ọlọrun sọ ara rẹ di Eniyan bi awa Oun f’ide ifẹ rẹ fa wa O si ra wa pada   3. Lori igi agbelebu Lọmọ Ọlọrun ku Oun f’ide ifẹ rẹ fa wa O fẹjẹ rẹ s’etutu   4. Ọm’ Ọlọrun s’ọjọ mẹta Ninu iho ilẹ Oun f’ide ifẹ rẹ fa wa O gba ‘gbara lọwọ ‘kus   5. Iku ko lagbara lori rẹ ‘Sa

Orin Kan: Ó Sì Bá Wọn Se Ìpinnu

Image
( “Ìjọba ọrun sa dabi ọkọnrin kan ti ise bale ile, ti o jade ni kutukutu owurọ lati pe awọn alagbase sinu ọgba ajara rẹ” (Matt. 20:1)) Ọrọ Àsọsíwájú Lati Ọwọ Onkọrin yi: Ngo mọ àwọn àmìn orin ti inu iwe daradara, sugbọn pẹlu awọn orin ti a ma nkọ nigbati mo wa lakọrin ati ninu ijọ gan bayi, mo ko orin titun yi jade. Bi o ba ti mọ orin to mbẹ nisale yi, ajẹ wipe o ti dara niyẹn darapọ mọ mi ki a jijọ kọ orin yi si Oluwa.   Ohùn Orin Inú Ìwe to yẹ ki a mọ Niyi “Sa gbẹkẹle l’ ọjọjọ Gbẹkẹle l’arin ‘danwo Bi ‘gbagbọ tilẹ kere Gbẹkẹle Jesu nikan Ègbè Gbẹkẹle ni ‘gbagbogbo Gbẹkẹle lojojumọ, Gbẹkẹle lọnakọna Gbẹkẹle Jesu nikan” Ẹniti o Kọrin Yi: Orin Titun na Nìyí 1. ‘Jọba ọrun sa dabi Ọkunrin bale ‘le kan To jade l’owurọ kutu Lọ pe awọn  alagbase Ègbè ‘Tor’ọpọ enia la pe Sugbọn di ẹ la o ri yan Lar’ awọn enia di ẹ na Jesu jẹ ki njẹ ọkan   2. ‘Gbato de arin ọja O ri awọn alagbase T’ wọn duro nsọri-sọri ‘Wọn nret’ ẹni t’ yo pe wọn È

Orin Kan: Oluwa, Ọlọrun Alanu

Image
  ( “Oluwa si rekọja niwaju rẹ, o si nkepe, Oluwa, Oluwa, Ọlọrun alanu ati olore-ọfẹ, onipamọra, ati ẹniti o pọ li ore ati otitọ” (Exo 34:6))   Ọrọ Àsọsíwájú Lati Ọwọ Onkọrin yi: Ngo mọ àwọn àmìn orin ti inu iwe daradara, sugbọn pẹlu awọn orin ti a ma nkọ nigbati mo wa lakọrin ati ninu ijọ gan bayi, mo ko orin titun yi jade. Bi o ba ti mọ orin to mbẹ nisale yi, ajẹ wipe o ti dara niyẹn darapọ mọ mi ki a jijọ kọ orin yi si Oluwa.   Ohùn Orin Inú Ìwe to yẹ ki a mọ Niyi “Mimọ, Mimọ, Mimọ, Olodumare Ni kutukutu n’Iwọ o gbọ orin wa Mimọ, Mimọ, Mimọ oniyọnu julọ Ologo mẹta lai olubukun” Ẹniti o Kọrin Yi: Reginald Heber (1826)   Orin Titun na Nìyí 1. Oluwa Ọlọrun oni ipamọra Alanu ati olore-ọfẹ ni Ọ ‘Wọ nikan ni o pọ l’ore at’otitọ ‘Wọ to np’anu mọ fun ẹgbẹgbẹrun   2. Oluwa Ọlọrun aniwọ nikan ni O le dari gbogbo ẹsẹ taba sẹ ji Ati irekọja, at’ aisedede gbogbo Niwọ ti f’ ẹjẹ rẹ parẹ pata   3. Oluwa Ọlọrun lotọ lo ndar’ ẹsẹ ji Sugbọn ki yo jẹ k’ẹlẹ