Posts

Showing posts from April, 2022

O Kan Ìwọ Náà (2)

Image
Ó KÀN ÌWỌ NÁÀ (2) Lati ọwọ ÒGÚNDÁRE OLÚSẸ́GUN OLÚFẸ́MI © ÒGÚNDÁRE OLÚSẸ́GUN OLÚFẸ́MI (2015) Email: segundare111@gmail.com Facebook: Olusegun Ogundare Twitter: Ogundare Olusegun Telegram: Olusegun O. Ogundare Vk.com: Olusegun Ogundare LinkedIn: Segun Ogundare Tumblr: olusegundare Veenner chat: Ogundare Olusegun O. WhatsApp: +2347037106880 Cellular: +2348026301717 ÒRÍ KẸRIN IDAJỌ ATI ÈRÈ AFURUNGBIN NÃ No ori yi ni a o ti wo idajọ ati ere afurungbin na. (1) Ìdájọ́ afurungbin na ko duro lori ìwà ati ise awọn olugbọ rẹ bikose wipe idajọ rẹ duro lori asẹ Ọlọrun to tẹle tabi asẹ Ọlọrun to pamọ. Eleyi ni wipe, nigbati a bá ran afurungbin na si ilu kan, tabi iletò kan tabi ijọ kan tabi orilẹ ede kan tabi boya eniyan kan, ohun to se pataki fun afurungbin na ni lati lọ jisẹ ti a ran si ilu tabi ijọ tabi orilẹ ede tabi ẹni na.... Boya awọn tabi ẹniti a ran-an si nã kò wa gbọ ọrọ Ọlọrun nã, tabi boya wọn ko gba ọrọ Ọlọrun na gbọ tabi gba ọrọ Olorun na wọle, ele