Posts

Showing posts from April, 2020

Coronavirus Period is Period of Liberation for Some

Image
1. There are some people Who have been riding On others to get Attentions of people   Tola, Health Worker, in Abuja 2. All over the world How they do this Is through socialization for When they meet 3. With others at the Public places like religious And worship centers they Will hear what they say 4. And use it on Social media or other Media converting that to Money through their 5. Sermons, prayer points, music Playlets, but they will not Acknowledge those people Neither would such people be 6. Given token out of The gains they have Made but now that Cannot happen for lockdown 7. Before this time, some Unknown composers works have Been stolen and they Have lost their 8. Copyright because they do Not have the capital To go to the Studio to wax their album 9. Some writers works have Been stolen by renown Authors and have been Published as theirs 10. While those people on Seeing such wo

Ó ti Múmi Gbàgbé Ìtìjú Ìgbà Èwe mi

Image
(Bíbélì wípé, “má bẹrù, nitori ojú ki yio ti ọ: bẹni ki o mase dãmu; nitori a ki yio dójú ti ọ; nitori iwọ o gbagbe itiju igba ewe rẹ, iwọ ki yio si ranti ẹgàn iwa opo rẹ mọ” (Isa. 54:4)) Àfiyesi Pàtàkì Lati Ọwọ Ẹnito kọ Orin yi: Ti a ba ti le mọ orin inu iwe yi, a ti mọ orin titun ti mo kọ yi niyẹn. Orin Inu Iwe na Niyi. Ẹ dide, Ọmọ igbala Ẹyin t’ẹ fẹ Oluwa Dide, ilu alagbara Ki ọta to de Sion Ègbè F’agbara rẹ kọrin kikan, Bi iro omi okun Nipa ẹjẹ Kristi Jesu, Awa ju asẹgun lọ Awa ju asẹgun lọ Awa ju asẹgun lọ Nipa ẹjẹ Kristi Jesu, Awa ju asẹgun lọ Orin Titun Na 1. Agbara rẹ ti pọ lapọju Jehofa nla Ọba wa Ọba angẹli at’eniyan To gbaiye ka ori omi Ègbè Ọlọrun’yanu l’ Ọlọrun yi Jehofa Oluwa wa ‘Tori o ti mu ki ngbagbe Itiju igba ewe mi Itiju igba ewe mi Itiju igba ewe mi ‘Tori o ti mu ki ngbagbe Itiju igba ewe mi 2. Ki a to bi mi ‘wọ mọ mi ‘Gba mow a ‘nu iyami Iwọ ti pe mi lorukọ ‘Wọ ya