O Kan Ìwọ Náà (2)
 
Ó KÀN ÌWỌ NÁÀ (2)  Lati ọwọ  ÒGÚNDÁRE OLÚSẸ́GUN OLÚFẸ́MI  © ÒGÚNDÁRE OLÚSẸ́GUN OLÚFẸ́MI (2015)  Email:         segundare111@gmail.com  Facebook: Olusegun Ogundare  Twitter: Ogundare Olusegun  Telegram: Olusegun O. Ogundare  Vk.com: Olusegun Ogundare  LinkedIn: Segun Ogundare  Tumblr: olusegundare  Veenner chat: Ogundare Olusegun O.  WhatsApp: +2347037106880  Cellular:     +2348026301717        ÒRÍ KẸRIN  IDAJỌ ATI ÈRÈ AFURUNGBIN NÃ  No ori yi ni a o ti wo idajọ ati ere afurungbin na.   (1) Ìdájọ́ afurungbin na ko duro lori ìwà ati ise awọn olugbọ rẹ bikose wipe idajọ rẹ duro lori asẹ Ọlọrun to tẹle tabi asẹ Ọlọrun to pamọ. Eleyi ni wipe, nigbati a bá ran afurungbin na si ilu kan, tabi iletò kan tabi ijọ kan tabi orilẹ ede kan tabi boya eniyan kan, ohun to se pataki fun afurungbin na ni lati lọ jisẹ ti a ran si ilu tabi ijọ tabi orilẹ ede tabi ẹni na....   Boya awọn tabi ẹniti a ran-an si nã kò wa gbọ ọrọ Ọlọrun nã, tabi boya wọn ko gba ọrọ Ọlọrun na gbọ tabi gba ọrọ Olorun na wọle, ele...