Orin Kan: Orin Àwọn Orin
( “Àdàbà mi, ti ó wà ninu pàlàpala okuta, ni ibi ikọkọ okuta, jẹ ki emi ri oju rẹ, jẹ ki emi gbọ ohun rẹ; nitori didun ni ohun rẹ, oju rẹ si li ẹwà” (O. S. 2:14)) Ọrọ Àsọsíwájú Lati Ọwọ Onkọrin yi: N go mọ àwọn àmìn orin ti inu iwe daradara, sugbọn pẹlu awọn orin ti a ma nkọ nigbati mo wa lakọrin ati ninu ijọ gan bayi, mo ko orin titun yi jade. Bi o ba ti mọ orin to mbẹ nisale yi, ajẹ wipe o ti dara niyẹn darapọ mọ mi ki a jijọ kọ orin yi si Oluwa. Ohùn Orin Inú Ìwe to yẹ ki a mọ Niyi “Mase foya ohunkohun Ọlọrun y’O tọ ọ Magbe ibi ikọkọ rẹ Ọlọrun y’O tọ ọ Ègbè Ọlọrun y’O tọ ọ Lojojumọ, lọna gbogbo On y’O ma tọju rẹ Ọlọrun y’O tọ ọ” ...